Teststreams

FREE YORUBA SCHEME OF WORK FOR JUNIOR SECONDARY SCHOOL –JSS 1–3 – FIRST TERM NAPPS

NAPPS SCHEME OF WORK SECONDARY 1ST TERM (JSS1 -JSS3) 1ST TERM EDE YORUBA(L1, L2, L3)(SAA KIN-INNI) OSE JSS 1 JSS 2 JSS 3 1.1 Alifabęęti Yoruba (a) konsonanti: b, d, f, g, gb, abbl. (b) FawęliAiranmupe:  a, e, ę, i, o, ǫ, u. (d) FawęliAranmupe: an, ęn, in, ǫn, ύn Atunyewoiroede: i) IroKonsonanti ii) IroFaweli Ede: Atunyewofonolojiede Yoruba 1.2 […]

NAPPS SCHEME OF WORK SECONDARY 1ST TERM (JSS1 -JSS3)

1ST TERM

EDE YORUBA(L1, L2, L3)(SAA KIN-INNI)

OSEJSS 1JSS 2JSS 3
1.1Alifabęęti Yoruba (a) konsonanti: b, d, f, g, gb, abbl. (b) FawęliAiranmupe:  a, e, ę, i, o, ǫ, u. (d) FawęliAranmupe: an, ęn, in, ǫn, ύnAtunyewoiroede: i) IroKonsonanti ii) IroFaweliEde: Atunyewofonolojiede Yoruba
1.2ItanIsedale Yoruba: (a) Itanisedale Yoruba lati iluMeka de Ile-ife. (b) Itanisedale Yoruba lati ori Oduduwa niIle-ifeAtunyewo as to jeyoninuiseolodun kin-inni bi i: i) Ikini ii) OgesiseabbiAsa: Asa isinkuniile Yoruba
1.3OrikiLitireso: (a) Litireso-Saajumo-on-ko, mo-on-ka. (b) OrikiLitiresoniede Yoruba. (d) AwoniwuloLitiresolawujo Yoruba.Litireso: Atunyewoawonewialohun Yoruba to jeyoninuiseoldun kin-inniLitireso: Ewialohunafemesinabalayebii, ijala, Ere-ode, Iwi Egungun, Oya pipe abbi
2.1Ami ohunlorioro Onisilebukan: (a) Alayesokiloriorisiiohunmeteeta: Ohunoke (/) Ohunisale ( ) Ohunaarin (-) (b) Ami ohunlorioroonisilebukan. Apeere: lo, wa, gba.Eyagbologun nipa ise won: i) Golohunibeere ii) GbolohunAse. iii) Gbolohunkani iv) GbolohunAyisodiArokoAlalaye
2.2Ile-Ife saajudide Oduduwa atiidagbasoke to baawujonaaAsa igbeyawoniile Yoruba: i) Ifojusode ii) Iwadii iii) AlarinaabbiAsa: Ogun pipin
2.3IrufeLitireso Yoruba (a) Ohuntilitireso je (b) Eka tilitireso Yoruba pin si (d) Awononati eka Yoruba kookan pin siLitireso: Asayaniwe, Ayoka.Litireso: AwonewialohunAjemesinabalayebii: Iyereifa, Sango pipe, Esu pipe.
3.1Amin ohunlorioroonisilebumaji: Ami ohunloriKonsonantiaranmupeasesilebubii: konko, Gbagan, OromboabbiEyagbolohun nipa ise won: i) GbolohunOnibo ii) GbolohunAsapejuwe iii) GbolohunAsaponle iv) GbolohunAsodorukoEde: Atunyewoawonapolaninugbolohunede Yoruba (ApolaorukoatiApola Ise)
3.2Awoneya Yoruba: (a) Ibiti won tedosi. (b) Orisiieya Yoruba bii- Egba, Ijesa, Awori, Ekiti abbi. (d) IpinletieyakookantedosiniOrile-edeNaijiria.Asa igbeyawoigbalode: i) Soosi ii) Yigisiso iii) KootuAsa: Asa to suyoninuawonewialohunti o je moesinabalaye – ijala, iwi Egungun, Sango pipe, Oya pipe.
3.3Awonohun to yaLitiresosotosiedeojoojumo. Bii: Owe, Akanlo-ede, Afiwe, Awitunwiabbi.Litireso: Asayaniwe (ayoka)Litireso: Asayanapileko.
4.1Silebu: (a) Ohuntisilebu je. (b) Darukoihunsilebu Ede Yoruba. (d) Ihunoroonisilebukan.Apeere: I-le, Na-ana-je abiiEyagbolohun nipa ihun won: i) Gbolohun Abode ii) Gbolohunolpoporoise iii) GbolohunAlakanpoEde: Gbolohunede Yoruba
4.2Ikininiaarineya Yoruba: I (a) Pataki Ikininile Yoruba (b) Ipotiomokunrinatiomobinrin maa n waniasikoti won n kiagbalagba. (d) IkiniojoojumoatiidahunIse Akanse (Project): i) Ise awujo Yoruba bi i: Eni hihun, ikokomimo, irinriroabbiAsa: Atunyewoawon Ere idarayaile Yoruba bi Bojuboju, Okototita, Ayo tita, Gbadigbadii.
4.3IpatiLitireso n ko lawujo Yoruba, bii: idanilaraya, ikonnilogbon, iwure, ikiloiwaabbi.Ewialohun to jemoayeye: Ekuniyawo, Dadakuada, Orin Etiyeri, Oku pipe, IgbalaabbiLitireso: KikaiweLitiresoapilekotiijoba yan.
5.1Akoto ede-oni: (a) Ohuntiakoto je. (b) Odunti a gbe Akoto ti a n lo lowo jade fun lilo. (d) Pataki atunsekikoede Yoruba sile lodeoni, kikosipeliatijoatisipeli ode-oniOnka Ede Yoruba: Ookanlelugba de OOdunrun (201-300)Ede: Atunyewoawoneyagbolohunedd Yoruba.
5.2Ikininiaarineya Yoruba II (a) Ikiniatiidahun fun awonasiko bi i: oginnintin, igbaotutu, ojo, oye, abbi (b) Ikiniatiidahun fun awonosisebii: Agbe, Akope, Alaro, Onidiri, abbi (d) Ikiniatiidahun fun awoneniyanotootobii: Oba, Aboyun, Abore, abbiIse akansekanniawujo Yoruba: (Projest Practice)Asa: Atunyewoasairan-araeni-lowo – Owe, aaro, ebese, esusu, ajo.
5.3LitiresoAlohun to je moayeye bi i: Rara, Ege, abbi (a) Agbegbeibiti a ti n lo won. (b) Iruayeyeti a n lo okookan won fun (d) Alayesokiloriokookan won.Litireso: Asayaniwe (Ayoka)Litireso: KikaiweLitireso to ijoba yan.
6.1Iwuloede Yoruba: – Ohun tie de je. – Awoniwuloede Yoruba bi i: Oro asirisiso, orinkikoniileijosin, Adura tabi IwureabbiOnka Ede Yoruba: Ookanleloodurun de Eddegbeta (301-500)Ede: Gbolohun Abode.
6.2LitiresoAlohun to je moesinibile. B.a: ese-Ifa, Sango pipe, Oya pipe, IjalaabbiAsa itojuoyunnionaabinibiati ode-oni:Asa: Itesiwajuloriasairan-ara-eni-lowo.
6.3Asa: “Iwuloede {Orin kiko, ewi kike, orosiso}Litireso: AsayaniwekikaLitireso: KikaiweLitiresotiijoba yan.
7.1Onka Yoruba (1 – 100): ItumoOnkaetoonka: Aropo (+) Le, iyokuro (-) din, isodipupo (x) lonaAkaye (Olorogeere/wuuru)Ede: Awe gbolohunede Yoruba.
7.2Bi asasejeyoninuede Yoruba:Ikini, Asowiwo, Iwaomoluabi, Iranra-eni-lowoabbiOmobibi: Itojuikoko, oroidileAsa: Awonorisaile Yoruba.
7.3AwonLitiresoApileko: ItanArokoOlorowuuruAsayaniwekikaLitireso: KikaiweLitiresotiijoba yan.
8.1AwonLitiresoApileko- ItanAroko:Itaninuiwe, Awoneda-itan, ifiwawedaabbiAkaye (onisoro-ngbesi)Ede: Atunyewo awe gbolohunede Yoruba (Oloriati awe gbolohunafarahe)
8.2Atunyewoonka lati 1-100 ookan de ogorun-un: 1. Ise siseloriarpo (+) atiiyokuro (-) awonfigoAsa Isomoloruko: Layeatijo: i) Ojoti Yoruba n somolorukolayeatijo. ii) Awonohuneloisomolorukolayeatijo iii) Orisiirisiorukoti Yoruba n somolayeatijo.Asa: Orisa Ogun
8.3Iwekika: LitiresoApilekoitanArokoOlorowuuruAsayanIwekikaLitireso: Kikaiwetijioba yan
9.1Isorioroninugbolohunede Yoruba: Oro oruko, oro-ise, oro-aropoorukoabbiEde: Akoto (Ipinnuloriakoto 1974)Ede: Ibasepolaarin awe gbolohunmejeeji
9.2Asa Isomoloruko:Ohuneloisomoloruko, orisiirisiiorukobii: Abiso, idile, AmutorunwaabbiAsa Isomoloruko: Igbagbo Yoruba nipa orisirisiiorukoniile Yoruba.Asa: Orisa Sango atiIfa-Orunmila.
9.3AwonLitiresoApileko: Ere-Onise (Dirama)AsayanIwekikaLitireso: KikaiweLitiresotiijoba yan.
10.1Aroko-orikiati liana kikoAroko.Ede: Akoto (Ipinnuloriakoto 1974)
10.2Asa Isinku: Ohuneloisinku, Awonigbese/ilanaisinku, OrisiiokusisinnileYoruba bi i: Oku oba, Abuke, AboyunabbiAsa Isomoloruko: Igbagbo Yoruba nipa orisirisiiorukoniile Yoruba.
10.3AwonLitiresoApileko: EwiAsayanIwekika
11.1ArokoatonisonaAlapejuwe: Ile-iwe mi.
11.2Oyejijenile Yoruba: Awonohunelooyenile Yoruba
11.3EwiApileko: ‘isenioogunise.
12 & 13Idanwosaayi

Download lesson notes and exam questions packs

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Searching bag close